HYMN 833

C.M (FE 870)
Awo ati, ija ohun ti ko dara ni



1.  A JA ni gbo-Ekun aja 

     Be l‘a sa s‘ede won 

     Ogidan, l'ola iju 

     L‘akomo l'ain obe.


2.  Sugbon enia l’a da nyin 

     E hu wa bi omo

     K‘e mase ba ara nyin ja 

     Ere ni k’e ma se.


3.  Bi Omo-rere Maria 

     Ni k’iwa nyin tutu 

     K’e po n’ife bi Oluwa 

     Jesu Om'Olorun.


4.  Eni jeje bi agutan

     Ti iwa Re wun ni 

     Enia ati Olorun 

     N’idagba Re si won.


5.  Oluwa gunwa bi Ona 

     L'ori ‘te Re lorun

     O nwo aw' omo t‘o n'ife 

     O si nsami si won.  Amin

English »

Update Hymn