HYMN 651

C.M.S 436 H.C 2nd Ed 382,
t.H.C 225 C.M (FE 677)
"Emi ki yio mu ninu eso ajara mo titi 
de ojo na, nigbati emi o si ba nyin mu 
u ni titu ni ljoba Baba mi" - Matt. 26:29




1.  OJO ko, ase na leyi

     Mo f’ara mi fun nyin

     E wo, mo f’eje mi fun nyin

     Lati ra nyin pada.


2.  O di nu joba Baba mi

     Ki mto tun ba nyin mu 

     Ghana ekun ko ni si mo 

     A o ma yo titi.


3.  Titi l'ao ma je onje yi

     K’o to di igba na

     Ka gbogb’aiye l’opolopo 

     Y’o ma je y’o ma mu.


4.  Bukun atorunwa y'o ma 

     Wa lor’awon t‘o nje 

     Ngo gbe or’ite Baba mi 

     Ma pes’aye fun won.


5.  Sugbon nisisiyi ago 

     Kikoro l'em'o mu 

     Emi o mu nitori nyin 

     Ago ‘rora iku.

6.  E ko le mo banuje Mi 

     E ko ti r'ogo Mi

     Sugbon e ma s’eyi titi 

     K'e ma fi ranti Mi.  Amin

English »

Update Hymn