HYMN 547

C.M.S  431 H.C 435 t.H.C 41 
L.M (FE 573)
“Emi lanje iye ni” - John.6:48



1.  JESU, ayo okan gbogbo 

     Orisun 'ye imole wa

     Nin' opo bukun aiye yi 

     Lainitelorun: a to wa.


2.  Otito re duro lailai

     Won gba awon to ke pe O la

     Awon ti owa O, ri O

     Bi gbogbo nin'ohun gbogbo.


3.  A to O we, Onje iye

     A fe je l'ara Re titi

     A mu ninu Re, Orisun 

     Lati pa ongbe okan wa.


4.  Ongbe Re sa ngbe okan wa 

     Nibikibi t‘ o wu k'a wa 

     Ghat' a ba ri O awa yo 

     Ayo nigbat’a gba O gbo.


5.  Jesu, wa ba wa gbe titi

     Se akoko wa ni rere

     Le okunkun ese kuro 

     Tan ‘mole re mimo s’aiye.  Amin

English »

Update Hymn