HYMN 453

t.H.C 271 (2nd Tune) 
8.8.8.8.4 (FE 478) Ps. 43:5
Tune: lja Dopin



1.  JESU, Olugbala, wo mi 

     Are mu mi, ara nni mi 

     Mo de lati gb'ara le O 

     Wo ‘simi mi.


2.  Bojuwo mi o re mi tan 

     Irin ajo na gun fun mi

     Mo nwa ‘ranwo agbara Re 

     Wo Ipa mi.


3.  Idamu ba mi lona mi 

     Oru sokun, iji si nfe 

     Tan imole si ona mi 

     ‘Wo Mole mi.


4.  Gba Satani ba tafa re

     Wo ni mo nwo, nko beru mo 

    Agbelebu Re l’abo mi, 

    Wo Alafia mi.


5.  Mo nikan wa leti Jordan

     Ninu ‘waiya‐ja jelo ni

     Wo ki yio je k’emi ri

     Wo lye mi. 


6.  Gbogbo aini, ‘Wo o fun mi 

     Titi d’opin l'onakona

     Ni ‘ye, ni 'ku titi Iailai 

     Wo gbogbo mi.  Amin

English »

Update Hymn