HYMN 386

(FE 409)
H.C 251 t.H.C 113. C.M
"Lojiji iro si iri orn wa, bi iro efufu 
IiIe” - Ise. 2:2



1.  'GBANI t‘Olorun sokale 
   
     O wa ni ibinu 

     Ara si nsan niwaju Re 

    Okunkun on ina.


2.  Nigbat‘o wa nigba keji 

     O wa ninu ife

     Emi, Re si ntu ni lara 

     B'afefe owuro.


3.  Ina Sinai ljo kini 

     T’owo re mbu soke 

     sokale jeje bi ade

     Si ori gbogbo won.


4.  Bi ohun eru na ti dun

     Leti Israeli

     Ti nwon si gbo iro ipe

     T‘o m'ohun angeli gbon.


5.  Be gage nigbat' Emi wa, 

     Ba le awon Tire

     lro kan si ti orun wa 

     Iro iji lile.


6.  O nkun, ife Jesu, o nkan

     Aiye ese yika 

     L'o kan alaigboran nikan 

     Ni aye ko si fun.


7.  Wa, Ogbon, ife, at'lpa 

     Mu ki eti wa si

     K'a ma so akoko wa nu

     Ki ‘fe Re le gba wa.  Amin

English »

Update Hymn