HYMN 377

(FE 398)
Tune: Jeka layo ninu Jesu



1.  EMl orun jare wa, 

     Wa gunwa s’okan wa 

     Ko se ‘le re ninu wa 

     Awa elese mbe O o.


2.  Gbat’a wa n’ile aiye

     A kun f’opo asise

     T’o nfa danwo wa ba wa 

     Oluwa ye, jowo gba wa o.


3.  Nigbati idanwo ba de 

     T'ara gbogbo le ko wa 

     Mura s'esin, ghadura 

     Jesu yio si wa gbe o Ieke.


4.  Nihin l‘ore le tan o

     Pelu baba at‘iya

     Mura s'esin, p'Oluwa 

     ‘Gbayi ni iwo mo Jesu l‘ore.


5.  T‘osan t‘oru I'Ongbo 

     Gbogbo imikanle re 

     Ki o to pe O gbo O 

     Bayi ni ileri re si O.


6.  Pe mi loru ati osan

     Pelu emi igbagbo 

     Gb'okan s’oke s‘Oluwa 

     Jehovah Jire yio silekun.


7.  F’lfe han k’o si ma se

     lse idariji niso 
  
     Mu'gbagbo pelu ‘se re 

     ‘Gbayi ni Jesu to gba o la.  Amin

English »

Update Hymn