HYMN 331

t.H.C 222 L.M. (FE 354)
"Emi li enti o mbe laye, ti o si ti ku si kiyesi,
Emi mbe laye titi loi Amin"- Ifi 1:8



1.  JESU ore elese ku,

     Awon omo Salem nsokun 

     Okunkun bo oju orun 

     Iseti nla se lojiji.


2.  Nihin l’a r’anu at’ife 

     Oba ogo ku f ’enia

     Wa! ayo kil’ a tun ri yi 

     Jesu t’O ku tun ji dide.


3.  Ma beru, "Oba, wa titi 

     Iwo t’a bi lati gba wa”

     K’e b’iku pe, ”Oro re da? 

     "Iboji, isegun re da?"


4.  E wipe, “Oba, wa titi,

     Iwo ta bi Iati gba wa,"

     K’e b’iku pe, “Oro re da?” 

     “iboji, isegun‘re da?”  Amin

English »

Update Hymn