HYMN 31

C.M.S. 31, C.H 159, t.H.C (FE 48)
64 C.M.
“lnu mi dun nigbati nwon wi fun mi
pe E je ka Io si ile Oluwa” - PS. 122:1


1.  BI mo ti yo lati gb'oro 

     Lenu awon ore, 

     Pe, ‘Ni Sion ni k'a pe si 

     K'a p'ojo mimo.


2.  Mo f‘onata at‘ekun re 

     Ile t'a se loso

     lle t’a ko fun Olorun 

     Lati fi anu han.


3.  S‘agala ile ayo na 

     Leya mimo si lo

     Omo Dafidi wa lor'ite 

     O nda ejo nibe.


4.  O gbo iyin at‘igbe wa; 

     Bi ohun eru re,

     Ti nya elese sib‘egbe 

     A nyo ni ‘wariri.


5.  K‘ ibukun pelu ibe na, 

     Ayo nigbakugba

     K‘a fi ore ati ore 

     F’awon ti nsin nibe.


6.  Okan mi bebe fun Sion 

     Nigbati emi wa;

     Nibe n'ibatan at'ore 

     At'olugbala wa.  Amin

English »

Update Hymn