HYMN 106

8.8.8.5



1.  YIN Oluwa, enyin mimo

     Awa ti je ni ‘gbese to?

     Je k'a mu gbogbo ini wa

     Wa pelu ayo.


2.  Jesus l'Oko t'o dara ju

     O nfun wa l'okun l'oju ‘ja

     lbi kan ko le de ba wa

     ‘Gbat‘ a gbekele.


3.  Gbekele yin le, eyin mimo

     Olododo l’Olorun wa

      Ko s'ohun to le, ya awon

      T‘O fe l‘odo Re.


4.  F'ore ofe Re pa wa mo

     K‘a le tubo faramo O

     Titi ao fi de ‘nu ogo

     At‘ ayo l‘orun.


5.  ‘Gbana l‘ ao de ibi mimo

     ‘Gbana l'a o si di mimo

      Ayo nla ti a ko so

     Ni y‘o je ti wa.  Amin

English »

Update Hymn