HYMN 855

8s 6s



1.  EMI at’ara ile mi

     Yoo ma sin Oluwa wa 

     Sugbon emi papa

     Yon f’iwa at’oro han 

    Pe mo mo Oluwa t’orun 

    Mo nf‘okan toto sin.


2.  Em’o f‘apere ‘re le le

     Un o mu idena na kuro

     Lodo om'odo mi

     Un o f'ise won han ni iwa mi 

     Sibe n‘nu 'se mi ki nsi ni

     Ola na ti ife.


3.  Emi ki y'o soro gb’ipe 

     Emi y'o pe tu ninu 

     Om‘eyin Olorun

     Mo si fe je eni mimo 

     Ki nsi fa gbogbo ile mi 

     S'oju ona orun.


4.  Jesu, b‘o ba da ‘na fe na 

     Ohun elo t'lwo fe lo 

     Gba s’owo ara Re

     Sise ife rere n'nu mi

     Ki nfi b'onigbagbo toto 

     Ti ngbe l’aye han won.


5.  Fun mi l'or’ofe toto 

     Nje! Emi de lati jeri 

     Yanu oruko Re

    Ti o gba mi lowo egbe 

    Ire eyi t’a mo l'okan 

    Ti gbogb’ahon le so.


6.  Emi t'o bo lowo ese

     Mo wa lati gba le mi la

     Ki nwasu dariji

     F‘omo, f‘aya f’omo ‘do mi 

     Lati mu won to ‘na rere 

     Lo si orun mimo.  Amin

English »

Update Hymn