HYMN 810

S.M. (FE 845) 
“Gbogbo aiye ni yio ma sin O"
 - Ps.66:4



1.  WA, rohin Re yika 

     K’a si korin ogo 

     Alagbara li Oluwa 

     Oba gbogbo aiye.


2.  On l'O da won ibu

     O pala fun okun

     Tire ni gbogb’ awon odo 

     At'iyangbe ile.


3.  Wa, wole n’ite Re 

     Wa, juba Oluwa

     lse owo Re l‘awa se, 

     Oro Re l'o da wa.


4.  Gbo ohun Re loni

     Ma si se mu binu

     Wa, bi eni ayanfe Re

     Jewo Olorun re.  Amin

English »

Update Hymn