HYMN 776

C.M.S 594 S.272 P.M (FE 810) 
"E ma wa inu lwo Mimo, nitori ninu 
won I‘enyin ni lye ainipekun"- John. 5:39



1.  E TUN won ko fun mi ki ngbo, 

     Oro ‘yanu t’Iye

     Je ki nsi tun ewa won ri

     Oro ‘yanu t’lye

     Oro lye at‘ewa ti nko mi n’igbagbo 

     Oro didun! Oro ‘yanu

     Oro ‘yanu t’lye.


2.  Kristi nikan l’o nfi funni 

     Oro ‘yanu at’lye

     Elese gbo ‘pe ife na

     Oro ‘yanu at’Iye

     L’ofe l‘a fifun wa, ko le to wa sorun! 

     Oro didun! Oro ‘yanu

     Oro ‘yanu t’lye.


3.  Gbe ohun ihinrere na 

     Oro ‘yanu at’lye 

     F’lgbala lo gbogbo enia 

     Oro ‘yanu at’lye

     Jesu Olugbala, we wa mo titi lai! 

     Oro didun! Oro ‘yanu!

     Oro ‘yanu at’lye.  Amin

English »

Update Hymn