HYMN 770

C.M.S 592 S.M. (FE 804)
"E ma ko won lati ma kiyesi
ohun gbogbo" - Matt. 28:20



1.  ENYIN ‘ranse Kristi 

     Gbo ohun ipe Re

     E tele bi t’o fonahan 

     A npe nyin s‘ona Re.


2.  Baba ti enyin nsin 

     O n’ipa to fun nyn 

     N‘igbekele ileri Re 

     E ja bi okunrin.

3.  Lo f’Olugbala han 

     Ati anu nla Re

     F’awon otosi elese 

     Ninu omo Adam.


4.  L’oruko Jesu wa

     A ki nyin, Ona re!

     A mbe Enit’ o ran nyin lo 

     K’O busi ise nyin.  Amin

English »

Update Hymn