HYMN 768

(FE 802)
"Wa pelu mi ni Paradise" - Luku 23:43
Tune: Jesu mo wa sodo re



1.  OJO Wura oj’Olorun 

     T’okan aise nin’ogbe na

     Nib’ayo nla ko si l’aiye 

     Bi tura ni Paradise.

Egbe: Paradise...Paradise

          A pe k'a to f’aiye sile 

          Nib’imole...Paradise 

          Jesu j‘Oba loke lohun.


2.  Subu ara, ese‘tiju

     Iku ‘dajo, Ida 'jo won 

     Dekun ese pare lohun 

     Aiye lo ni Paradise.

Egbe: Paradise...


3.  Ko s’adura, ko si ewu 

     Ko s’edun mo, ipo sofo 

     Boji ati ibanuje

     Ko si won ni Paradise.

Egbe: Paradise...


4.  Krist’Oluwa lori igi 

     Elese ke, pe ranti mi 

     Loni ‘wo y’o Oluwa wi 

     Pelu mi ni Pradaise.

Egbe: Paradise...


5.  Ojo wura, gba Krsiti ji 

     Boji sile, aro si pin 

     Ogo nla bo, oku ji, y’o 

     Ba joba ni Paradise.

Egbe: Paradise...


6.  Kerubu ho, Serafu yo 

     Eyi ko ha t’ayo re bi 

     Pe Jesu la ona ‘gbala 

     Lati aiye lo de orun.

Egbe: Paradise...


7.  Tera-mose, ni ere re 

     Lati le ri ‘hin rere je

     K’a ma kuna Paradise 

     Ope ni fun Metalokan.

Egbe: Paradise...Paradise

          A pe k'a to f’aiye sile 

          Nib’imole...Paradise 

          Jesu j‘Oba loke lohun.  Amin

English »

Update Hymn