HYMN 762

H.C 541 6s (FE 796)
"Mo gbo ohuu kan Iati orun wa nwipe 
ibukun ni fun oku ti o ku nipa ti Oluwa"
- Ifi.14:13



1.  IBUKUN ni f'oku 

     T'o simi le Jesu

     Awon t’o gb‘ori won 

     Le okan aiya Re.


2.  Iran ‘bukun l'eyi 

     Ko si ‘boju larin

     Nwon ri En‘imole 

     Ti nwon ti fe lairi.


3.  Nwon bo Iowo aiye

     Pelu aniyan re

     Nwon bo lowo ewu 

     T’o nrin l'osan, l’oru.


4.  Lori iboji won

     L'awa nsokun loni 

     Nwon j'eni ire fun wa

     T'a kl y'o gbagbe lai.


5.  A k' y'o gbohun won mo

     Ohun ife didun

     Lat’ oni lo, aiye

     Ki o tun mo won mo.


6.  Enyin oninure 

     E fi wa sile lo

     Ao sokun nyin titi 

     Jesu pa sokun ri.


7.  Sugbon a fe gbohun 

     Olodumare na

     Y’o ko, y‘o si wipe 

     E dide, e si yo.  Amin

English »

Update Hymn