HYMN 759

H. C 544 7.7.7.7.8.8 (FE 793)
“Ki emi ki o to lo kuro nihinyi, ati ki 
emi ki o to se alaisi” - Ps. 39:13



1.  LALA alagbase, tan; 

     Ojo ogun ti pari;

     L’ebute jijin rere,

     Ni oko re ti gun si. 

Egbe: Baba, Iabe itoju Re,

          L‘awa f’iranse Re yi si.


2.  Nibe l’a re won l’ekun 

     Nibe, nwon m’ohun gbogbo

     Nibe l’onidaj’ oto 

     Ndan ise aiye won wo.

Egbe: Baba, Iabe...


3.  Nibe l’olus’agutan 

     Nko awon agutan lo,

     Nibe l’o ndabobo won, 

     Koriko ko le de ‘be.

Egbe: Baba, Iabe...


4.  Nibe l’awon elese

     Ti nteju m’agbelebu,
   
     Y’o mo ife Kristi tan 

     L’ese Re ni Paradise.

Egbe: Baba, Iabe...


5.  Nibe l'agbara Esu,

     Ko le b’ayo won je mo

     Krist Jesu sa nso won;

     On t’o ku dande won. 

Egbe: Baba, Iabe...


6.  ‘Erupe fun erupe 

     L’ede wa nisisi 

     A te sile lati sun 

    Titi d’ojo ajinde.

Egbe: Baba, Iabe itoju Re,

          L‘awa f’iranse Re yi si.  Amin

English »

Update Hymn