HYMN 755

C.H. 372 t.H.C 140 C.M (FE 789)
“Alabukun fun li awon oku ti o ku
nipa ti Oluwa” - Ifi.14:13



1.  GB'ohun t’o t‘orun wa ti wi 

     F’awon oku mimo

     Didun n‘irant’oruko won 

     Busun won n’itura.


2.  Nwon ki n’nu Jesu abukun 

     Orun won ti dun to!

     Ninu irora on ese

     Nwon yo ninu danwo.


3.  Lona jijin s’ayie ise 

     Nwon mbe lod’Oluwa 

     Ise won l‘aiye iku yi 

     Pari li ere nla.  Amin

English »

Update Hymn