HYMN 735

C.M. (FE 761)
“Ma beru ohun ti wio yio je niya iwo 
se oloto de oju iku, emi yio si fi ade 
iye fun o" - Ifi. 2:10 
Tune: lsun kan wa to kun f’eje



1.  ENYlN om’egbe Serafu 

     E ko le p’e o ko ‘ya 

     Enyin om eghe Kerubu 

     E ko le pe e o ko ya.


2.  Enyin om'ogun gbala yi 

     E ko le pe e o k’egan 

     E ko le ko ‘nunibini 

     Ati keta gbogbo.


3.  E gb’ohun Olugbala wa 

     B’o ti nwi jeje pe

     Ranti mi lor’agbelebu 

     At, owo at'ese.


4.  Bi a ba foriti ‘ponju 

     Ti a si ru ‘tiju

     Ade ogo ‘rawo Owuro 

     Y’o je tiwa n‘kehin.


5.  Ao pelu awon t’orun 
  
     Lati ma juba Re

     A o si ma ko orin Mose 

     Ati t’Odagutan.


6.  Orin Halle, Halleluya! 

     lyin si Oba wa 

     Metalokan Aiyeraiye 

     Baba, Omo, Emi.  Amin

English »

Update Hymn