HYMN 725

P.M



1.  AWA f’ori bale fun/O Jesu

     Wo ti s’Olori ljo awon/eniyan Re 

     Ijo ti mbe laye yi ati lo/run pelu 

     Ale/luya.


2.  Wo t‘oku, t‘o si jin/de fun wa

     T’o mbe lodo Baba bi Ala/gbawi wa 

     K‘ogo atolanlan/je Tire

     Ale/luya.


3.  Ati li ojo nla Pen/tikosi

     Ti o ran Paraklitj/si aye 

     Olutunu nla Re ti/mba wa gbe 

     Ale/luya.


4.  Lat’ori ite Re l’ok/ke orun

     L'o o si nwo gbogbo awon o/jise Re 

     T'o si nsike gbogbo awon Aje/riku Re 

     Ale/luya.


5.  A fi iyin at'olanlan f’o/ruko Re 

     N'tori iku gbogbo awon o/jise Re

     Ni gbogbo ile, Yo/ruba yi 

      Ale/luya.  Amin

English »

Update Hymn