HYMN 695

H.C 231:tabi t.H.C 205. D.C.M
"Oluwa awon omo-ogun, On na
Ii Oba ogo" - Ps. 24:10



1.  GBE ori iyin s’oke, eyin 

     ‘Lekun aiyeraiye:

     Gba oba ogo: wo, o mbo 

     Pel’ogun orun Re.

     Ta l'Oba Ogo yi? Tani? 

     Oluwa t'o ni ipa

     T’o lagbara l’o or’ota Re 

     Asegun, Alade.


2.  Gbe ori yin s‘oke, enyin 

     Ilekun; lati gbaa

     Oba ogo, pe we, o mbo 

     Pel’ ogun didan Re 

     Tal’oba Ogo yi?

     Oluwa t‘o n’ipa

     L’ogo on nikan Ii oba 

     Ta f'ogo de l’ade.  Amin

English »

Update Hymn