HYMN 693

C.M.S 575 K. 454 t.H.C
"Jeki oju Re siu si ile yi Ii osan ati
Ii oru.." - 1Oba 8:29



1.  A FI ipile yi le le

     Ni oruko Re Oluwa

     Awa mbe O Oluwa wa, wa 

     Ma toju ibi mimo yi.


2.  Gba enia re ba nwa O 

     T'elese nwa, O n‘ile yi 

     Gbo, Olorun, lat’ orun wa 

     F'ese ji won, Olorun.


3.  Gb‘awon Alufa ba nwasu 

     lhinrere ti Omo Re,

     Ni oruko Re, Oluwa

     Ma sise iyanu nla re.


4.  Gb'awon omode ba si nko 

     Hosannah si Oba won

     Ki Angeli ba won ko pelu 

     K'orun at’aiye jo gherin.


5.  Jehovah, o ha ba ni gbe 

     Ni aiye buburu wa yi 

     Jesu, o ha je Oba wa 

     Emi o ha simi nihin?


6.  Ma je ki ogo re kuro

     Ninu ile ti a nko yi 

     Se ‘joba Re ni okan wa,

     Si te ite Re sinu wa.  Amin

English »

Update Hymn