HYMN 686

461 H.C 493. 6s 5s 
"Tani ha nkegan ohun ojo
kekere" - Sek. 4:10



1.  OPO ikan omi 

     Yanrin kekeke

     Wonyi l‘o d’okun nla 

     At'ile aiye.


2.  Iseju wa kokan 

     Ti a ko ka si

     Lo d'odun aimoye 

     Ti ainipekun.


3.  lwa ore die

     Ore'fe die

     L‘o ns‘aiye di Eden 

     Bi oke orun.


4.  lsise kekeke

     Lo nmokan sina

     Kuro l’ona rere 

     Si ipa ese.


5.  lse anu die
 
     T’a se l’omode 

     Di ‘bukun f'orile 

     To jina rere.


6.  Awon ewe logo

     Ngberin Anglei

     Se wa ye, Oluwa, 

     F'egbe mimo won.  Amin

English »

Update Hymn