HYMN 685

C.M.S 482 t. H.C. 36.8s (FE 710)
"E fi iberu sin Oluwa” - Ps. 2:11



1.  OMODE, e sunm’ Olorun 

     Pelu irele at’eru

     Ki ekun gbogbo wole fun 

     Olugbala at'Ore wa.


2.  Oluwa, je k’anu Re nla 

     Mu wa kun fun ope si O

     Ati b‘a ti nrin lo laiye 
 
     K‘a ma ri opo anu gba.


3.  Oluwa! m‘ero buburu

     Jina rere si okan wa 

     L;'oiujumo fun wa I‘Ogbon 

     Lati yan ona toro ni.


4.  lgba aisan at‘ilera 

     lgba aini tabi oro

     Ati lakoko iku wa

     Fi agbara Tire gba wa.  Amin
 

English »

Update Hymn