HYMN 673

C.M.S 466 S. 17 8. 6. 8. 5 (FE 669) 
"Nwon o si je temi Ii Oluwa awon 
Omo-ogun wi, li ojo na nigbati mo 
ba nsiro oso mi" - Mal.3:17



1.  GBAT' O ba de gbat' o ba de 

     Lati sir’oso Re

     Gbogb;'oso Re iyebiye

     Awon ti o fe.

Egbe: Bi irawo owuro, nwon

           ns’ade Re loso

           Ewa won o yo pupo 

           Ewa f’ade Re.


2.  Yio ko jo, yio ko jo

     Oso ijoba Re,

     Awon mimo, awon didan 

     Awon ti ofe.

Egbe: Bi irawo...


3.  Awon ewe, awon rere 

     T‘o fe Olugbala

     Ni oso Re iyebiye 

     Awon ti o fe.

Egbe: Bi irawo owuro, nwon

           ns’ade Re loso

           Ewa won o yo pupo 

           Ewa f’ade Re.  Amin

English »

Update Hymn