HYMN 666

C.M. (FE 692)
"Egbe buburu ko se ko"



1.  AWON asepe, abura 

     At’awon onija

    Ni ijo kan pelu abo 

    Niki y’o je s’owo won.


2.  Orin buburu ti nwon nko 

     Je rira l’eti mi

     K’iru oro buburu won 

     Mase t’enu mi bo.


3.  Awon alailero omo 

     Awon Omo-komo

     Ki y’o f;’ijo kan j'egbe mi 

     A f‘ologbon omo.


4.  Alailojuti omo kan 

     Ni b‘awon t'o ku je 

     Elekuru obuko kan 

     Ni ko orun w’agbo.


5.  Ma je kl nk'egbe buburu 

     Olorun Oluwa,

     Ki nma si si ninu won

     Ti nlo s'orun egbe!  Amin

English »

Update Hymn