HYMN 656

11s 10s (FE 682)
“Ife lakoja ofin" - 1Kor. 13:13
Tune: Emi l'Olorun awon ti ba nsin



1.  IFE pipe t’o tayo ero eda

     L’ebe l’a kunle niwaju ‘te Re 

     Jowo f’ife ti ki y’o lopin sarin 

     Awon t’lwo so sokan po lailai.


2.  lye pipe jowo f‘aiya won bale 

     Nipa ife ati ‘gbagbo yiye

     Ti suru, ireti, at’ifarada

     Pelu igbekele ti ko le ye.


3.  Jo fun won l’ayo ti y’o

     m‘aiye won dun

     Alafia ti y’o segun ija

     Si f’ife aiyeraiye ati Iye

     Kun okan won titi d‘ojo Ogo.  Amin

English »

Update Hymn