HYMN 645

S.S 372 (FE 671)
"Ilekun na si sile fun mi"
- Ifihan 21:25



1.  LEKUN kan mbe t'o sipaya 

     lati inu ona re wa

     Mole lat’ ori agbelebu 

      Nf'lfe Olugbala han.

Egbe:  A Anu jinle o le je

           Pe 'Iekun na si sile fun mi 

           Fun mi? - Fun mi? 

           Pe o si sile fun mi.


2.  Lekun na si sile lofe

     Fun gbogbo eni nfe igbala

     F;Oloro ati talaka 

     Fun gbogbo orile-ede 

Egbe:  A Anu jinle o le je...


3.  Te siwaju b’ota nrojo 

     Ghati lekun na si sile 

     Gb’agbelebu jere ade 

     Anu ife ailopin.

Egbe:  A Anu jinle o le je...


4.  Gba ba d’oke odo lohun 

     Ao gb’agbelebu sile

     Ao bere gb’ade iye

     Ao fe Jesu si l’orun.

Egbe:  A Anu jinle o le je

           Pe 'Iekun na si sile fun mi 

           Fun mi? - Fun mi? 

           Pe o si sile fun mi.  Amin

English »

Update Hymn