HYMN 643

t.s. 338 or SSS 874 P.M (FE 669) 
“Awa ri ile kan lati odo Olorun ile ti
a ko fi owo ko" - 2Kor.5:1



1.  KINl y;'o Kehin aiye? 

     Kerubu pelu Serafu 

     Gege bi oko Noah 

     Kerubu pelu Serafu 

     Olorun Elijah
   
     T‘o k’awon enia re 

     L’aginju aiye ja 

     Kerubu pelu Serafu.


2.  Irawo gbogbo wa ntan 

     Kerubu pelu Serafu 

     Egbe Mimo wo l‘eyi? 

     Kerubu pelu Serafu 

     Olorun Kerubu

     T’o k'awon enia re 

     L’aginju aiye ja 

     Kerubu pelu Serafu.


3.  Gbo, nwon nko Halleluya! 

     Kerubu pelu Serafu

     Orin iyin s’Oba wa 

     Kerubu pelu Serafu 

     Olorun Serafu

     T’o k’awon enia re 

     L’aginju aiye ja 

     Kerubu pelu Serafu.


4.  Gbo, Eda orun nkorin 

      Kerubu pelu Serafu 

      Eda aiye ko gberin 

      Kerubu pelu Serafu

      A gboju wa soke 

      S’Olorun Alaye 

      Gb’adura edun wa 

      Kerubu pelu Serafu.


5.  Mimo, Mimo l'Olorun 

     Kerubu pelu Serafu 

     Olorun Metalokan 

     Kerubu pelu Serafu 

     Olorun Abraham 

     Olorun lsaaki

     Olorun Jakobu 

     Kerubu pelu Serafu.


6.  Ogo f'Olorun Baba 

     Kerubu pelu Serafu 

     Ogo f'Olorun Omo, 

     Kerubu pelu Serafu 

     Ogo f'Emi Mimo 

     Metalokan lailai

     T’o degbe yi sile

     Kerubu pelu Serafu.  Amin

English »

Update Hymn