HYMN 624

(FE 650)
“Mo gb’ohun Re" - Gen. 3:10



1.  MO gb'ohun Re ninu ala mi 

     Ohun kelekele

     Ohun ti nso ‘fe t’Oluwa

     Ife irapada

     Mo te’ti lele lati gbo 

     O si ya mi lenu. 

     Jo jeki nroju Re. 

Egbe:  Jo jeki nroju Re - 2ce 

           Bi mo ti te ‘ti le le to 

           Jo jeki nroju re.


2.  Ninu wahala aiye mi 

     Mo ba Jesu pade

     Ti O si gba mi niyanju 

     Lati ma gbadura

     Mo te’ti le le lati gbo

     O si mu ‘nu mi dun

     O si tun ki mi l’aiya pe 

     Ki nsa ma gba adura.

Egbe:  Ki nsa ma gba 'dura - 2ce 

           O si tun ki ni I‘aya pe 

           Ki nsa ma gba adura.


3.  Olodumare jo gba wa 

     Awa Egbe Serafu 
 
     Nigbati wahala ba de 

    Jo gbo adura wa

    Ran awon Kerubu si wa 

    Lati ran wa lowo

    Ki O si te ‘ti si igbe wa 

    K’O gbo adura wa.

Egbe:  K'O gbo adura wa - 2ce

            Ki O si te 'ti si igbe wa 

            K’O gbo adura wa.  Amin

English »

Update Hymn