HYMN 622

t. H.C 465 7s (FE 648)
“E ma si de da won lekun" - Marku 10:14



1.  JESU Baba omode 

     Ase re ni awa nse

     A m’omo yi wa ‘do Re 

     Ki iwo so di Tire.


2.  Ninu ese ni a bi

     We kuro nin’ese re

     Eje re ni a fi ra

     K'opin ninu Ebun Re.  Amin

English »

Update Hymn