HYMN 618

C.M.S 446, t.H.C. 149. C.M (FE 644)
“Bikosepe a tun enia bi nipa omi ati 
nipa Emi, On ki yio le wo Ijoba 
Orun" - John 3:5


1.  EY l'ase nla Jehovah 

     Yio wa titi lai

     Elese b’lwo at’emi

     K‘a tun gbogbo wa bi.


2.  Okunkun y‘o je ipa wa 

     B’a wa ninu ese

     A ki o ri ijoba Re

     Bi a ko d'atunbi.


3.  Bi baptisi wa je’gbarun 

     Asan ni gbogbo re

     Eyi ko lew’ese wa nu

     Bi a ko tun wa bi.


4.  Wo ise were ti a nse

     Koni iranwo re

     Nwon ko s‘okan wa di otun

     B’awa ko d‘atunbi.


5.  Lo kuro ninu ese re

     Ja ewon Esu nu

     Gba Kristi gbo tokantokan

     lwo o d’atunbi.  Amin

English »

Update Hymn