HYMN 613

O.t.H.C 245 S.M (FE 639) 
“Kini iwo si duro si nisisiyi? dide 
ki a baptist re, ki iwo ki o si we 
ese re nu, ki o si mape oruko 
Oluwa" - Ise.22:16



1.  DURO, omo ogun 

     F’enu re so f’aiye

     Si jeje pe o ofo l’aiye 

     Nitori Jesu re.


2.  Dide k’a baptis’ re

     K’a we ese re nu

     Wa b‘Olorun da majemu 

     So ‘gbagbo re loni.


3.  Tire ni Oluwa

     At’ijoba orun

     Saa gb’ami yi siwaju re 

      Ami Oluwa re.


4.  Wo k’ise t’ara re 

     Bikose ti Kristi

     A ko oruko re po mo 

     Awon mimo gbani.


5.  Ni hamora Jesu

     Kojuja si Esu

     B’o ti wu k’ogun na le to 

     Iwo ni o segun.


6.  Ade didara ni

     Orin na, didun ni

     Gbat t‘a ba ko ikogun jo, 

     S’ese Olugbala.  Amin

English »

Update Hymn