HYMN 611

P.M (FE 637)



1.  WA sodo Jesu, mase duro 

     L’oro Re l’O ti f’ona han wa 

     O duro li arin wa loni

     O nwi jeje pe ‘Wa.

Egbe: Ipade wa yio je ayo

          Gb’okan wa ba bo Iowo ese

          T’a o si wa pelu Re Jesu 

          Ni ile wa lailai.


2.  Jek’ omode wa, A gbohun Re

     Jek’okan gbogbo ho fun ayo

     Ki a si yan On l’ayanfe wa

     Ma duro sugbon wa.

Egbe: Ipade wa yio je ayo...


3.  Tun ro o wa pelu wa loni 
 
     F’eti s’ofin Re, k’o si gbagbo 

     Gbo b’ohun Re ti nwi pele, pe 

     Enyin omo mi wa.

Egbe: Ipade wa yio je ayo

          Gb’okan wa ba bo Iowo ese

          T’a o si wa pelu Re Jesu 

          Ni ile wa lailai.  Amin

English »

Update Hymn