HYMN 606

11s (FE 632)
"Emi o kigbe pe O, Oluwa, ati si 
Oluwa li emi mbebe gidigidi"
 - Ps. 30:8



1.  GBE ‘banuje re mi 

     o ka ri aiye

     Fi s‘ohun igbagbo 

     roju pa mora

     Fi suru ronu re/li oru ‘ganjo

     To Jesu lo ro fun/yio si san fun o.


2.  To Jesu lo, ro fun, O mo edun re, 

     To Jesu lo, ro fun, yio ran o lowo 

     Lo je k’adun ayo/to pese fun O 

     Yio m’eru re fuye/sa lo gbadura.


3.  Awon ti osi won/po ju tire lo

     N’sori ko n‘nu okun, lo tun won ninu 

     Gbe ‘banuje re mi, f’elomi layo

     Lo tan ‘mole fun won

     f’abo fun Jesu.  Amin

English »

Update Hymn