HYMN 603

(FE 629)
“Oluwa awon omo-ogun, ibukun ni
fun eni no ti ogbekle O" - Ps. 84:12
Tune: Ikore aiye fere gbo



1.  E DIDE omo igbala

     To romo Olori wa

     E dide orile ede

     Ki ota to de Sion.

Egbe:  E ko orin, to dun pupo

           E korin to dun pupo

           Bi hiho omi okun

           Nipa eje Olugbala

           Awa ju asegun Io- asegun lo

           Awa ju asegun lo- asegun.


2.  E wa bu omi igbala

     Enyin omo araiye

     E wa gba igbala lofe

     T’Oluwa pese fun wa.

Egbe:  E ko orin, to dun pupo...


3.  Jesu f'ogoj’odun bebe

     Fun Egbe Serafu yi

     Lati fi ra aiye pada

     Ninu ese wa gbogbo.

Egbe:  E ko orin, to dun pupo...


4.  Ogo ni fun Baba, Omo

     Emi Mimo lo de yi
   
     Jowo fo gbogbo wa mo lau

     Nini ese wa gbogbo.

Egbe:  E ko orin, to dun pupo

           E korin to dun pupo

           Bi hiho omi okun

           Nipa eje Olugbala

           Awa ju asegun Io- asegun lo

           Awa ju asegun lo- asegun.  Amin

English »

Update Hymn