HYMN 601

C.M. 388 H.C. 179 11 10s (FE 627)
"Wasu ihinrere fun gbogbo eda"
- Mark. 16:15



1.  YO awon ti nsegbe

     Sajo eni nku

     F‘anu ja awon kuro ninu ese,

     Ke f'awon ti nsina, gb‘eni subu ro,
  
     So fun won pe, Jesu le gba won la.

Egbe:  Yo awon ti nsegbe

           Sajo eni nku lo

           Alanu ni Jesu, yio gbala.


2.  Bi nwon o tile, gan

     Sibe, O nduro

     Lati gb‘omo t‘o ronupiwada

     Sa f ‘itara ro won, si ro won jeje

     On o dariji, bi nwon je gbagbo.

Egbe:  Yo awon ti nsegbe...


3.  Yo awon ti nsegbe Ise tire ni

     Oluwa yio f‘agbara fun O

     Fi suru ro won pada s’ona toro

     So f’asako p’Olugbala ti ku lo.

Egbe:  Yo awon ti nsegbe

           Sajo eni nku lo

           Alanu ni Jesu, yio gbala.  Amin

English »

Update Hymn