HYMN 573

S. 8. 5 (FE 600)
"Sugbon eyi ti enyin ti gbe e di mu
sinsin titi emi o fi de" - Ifi.2:25



1.  HA! egbe mi, e w’asia 

     Bi ti nfe lele

     Ogun Jesu fere de na 

     A fere segun. 

Egebe: D'odi mu, emi fere de 

             Beni Jesu nwi

             Ran dahun pada s’orun pe 

             Awa o dimu.


2.  Wo opo ogun ti mbo wa, 

     Esu nko won bo

     Awon alagbara nsubu

     A fe damu tan!

Egebe: D'odi mu...


3.  Wo asia Jesu ti nfe 

     Gbo ohun ipe

     A o segun gbogbo ota 

    Ni oruko Re.

Egebe: D'odi mu...


4.  Ogun ngbo ‘na girigiri 

     Iranwo wa mbo 

     Balogun wa mbo wa tete 

     Egbe tujuka.

Egebe: D'odi mu, emi fere de 

             Beni Jesu nwi

             Ran dahun pada s’orun pe 

             Awa o dimu.  Amin

English »

Update Hymn