HYMN 567

H.C 364 8s 7S (FE 594) 
“Ese ti enyin fi sojo be?"
 - Matt.8:26



1.  ESE d’eru? wo, Jesu ni! 

     On tika’Re l’o ntoko

     E ta gbokun si afefe 

     Ti y’o gbe wa la ibu 

     Lo si ilu

     Bit’ olofo ye sokun.


2.  B’a ko mo bit’a nlo gun si 

     Ju b’ati ngbohin re lo 

     Sugb'a ko ‘hun gbogbo sile 

     A tele ihin t’a gbo

     Pelu Jesu

     A nla arin ibu lo.


3.  A ko beru igbi okun

     A ko si ka iji si

     Larin rukerudo, a mo

     P’Oluwa mbe nitosi

     Okun gba gbo

     lji sa niwaju Re. 

 
4.  B'ayo wa o ti to lohun 

     lji ki ja de ibe

     Nibe l'awon ti nsota wa 

     Ko le yo wa lenu mo 

     Wahala pin

     L'ebute alafia na.  Amin

English »

Update Hymn