HYMN 553

S.I 8:5 (FE 580)
Tune: Ha! Egbe mi E w’asia
“Awa ki yio beru” - Ps. 46:2



1.  EGBE Seraf’e w’asia 

     Bo ti nfe lele

     Awa Kerub’ si ti mura 

     Awa yio segun.

Egbe:  Nde Baba Aladura nde 

           Jesu lo ran O

           Awa Omo Re ti mura 

           Awa ki yio beru.


2.  Wo Satan pel‘ogun re 

     Maikiel fon won ka 

     Awon Alagbara subu 

     Seraf‘ te won pa.

Egbe:  Nde Baba Aladura...


3.  Jesu Olugbala wipe 

     Emi fere de

     A si ayo dahun pe

     E dide asegun.

Egbe:  Nde Baba Aladura...


4.  Nigbati ogun ba gbona

     O pe, Ma beru

     L'o to Balogun wa Maikiel 

     Si fa da re yo.

Egbe:  Nde Baba Aladura...


5.  Wo Asia Jesu ti nfe

     Ohun lpe ndun

     Mose yio segun gbogbo ota 

     Lagbara Jesu.

Egbe:  Nde Baba Aladura nde 

           Jesu lo ran O

           Awa Omo Re ti mura 

           Awa ki yio beru.  Jesu

English »

Update Hymn