HYMN 533

C&F 562: Y.L.C 43 S.S & S 59 
(FE 559)



1.  IFE to fi wa emi ti eru ese npa

     O fi owo Re fa mi mora pada s'agbo 

     Angeli nfi ayo korin pelu

     awon ogun orun.

Egbe:  A! ife t'o wa mi, A!

           Eje t'o ra mi

           Suru pelu ore-ofe Re

           To fa mi pada bo, wa s'agbo!


2.  O w’ese mi nu kuro k‘emi 

     Le di mimo

     O so fun mi jeje pe‐lwo 

     sa je t'emi

     Ko si ohun to dun t'eyi lo

     mu alare okan yo. 

Egbe:  A! ife t'o wa mi, A!...


3.  Emi y’o wa si ‘hin yi, ile 

     owo mimo

     Pelu okan igbagbo, lati 

     toro bukun

     O dabi enipe ojo ngun lati

     fi iyin Re han. 

Egbe:  A! ife t'o wa mi, A!...


4.  Nje nigbat‘ orun ba wo 

     t’ojo oni si lo

     Ngo se’reti owuro ti yio 

     mu ayo wa!

     Titi ao fi pe mi lati bo

     sinu isimi Re.

Egbe:  A! ife t'o wa mi, A!

           Eje t'o ra mi

           Suru pelu ore-ofe Re

           To fa mi pada bo, wa s'agbo!  Amin

English »

Update Hymn