HYMN 528

C.M.S 346 O. t.H.C 320 
C.M (FE 553)
"E ma ru eru omonikeji nyin"
 - Gal. 6:2



1.  ALABUKUN ni fun ife 

     Ti ki oje k’a ya

     Bi ara wa jina s’ara 

     Okun wa wa l’okan.


2.  Da opo Emi s‘ori wa 

     Ona t’Ola l’a nto 

     Nipa ti Jesu l’a si nrin 

     Iyin Re l'a nfi han.


3.  Awa ba ma rin l‘ona Re 

     K’a ma sin m’ohun kan

     K’a ma fe ‘hun kan, bikose 

     Jesu t’a pa fun wa.


4.  K'a sunmo O girigiri

     Ati si ona Re

    K‘a ma r’ore gba lodo Re 

    Ekun ore-ofe.  Amin

English »

Update Hymn