HYMN 524

C.M.S 342 H.C 300 S.M 
2nd Ed (FE 549)
"Nigbati nwon ko si rti ti nwon o san, 
tinutintu Ii o dariji awon mejeji"
 ‐ Luke.7:42




1.  O FUN mi l’edidi 

     Gbese nla ti mo je

     B’o ti fun mi, o si rerin 

     Pe, Mase gbagbe mi’.


2.  O fun mi l’edidi

     O san igbese na

     B’oti funmi, O si rerin 

     Wipe, Ma ranti mi!


3.  Ngo p’edidi na mo 

     B’igbesi tile tan

     O nso ife enit’ o san 

     lgbese na fun mi.


4.  Mo wo, mo si rerin 

     Mo tun wo, mo sokun 

     Eri ife Re si mi ni 

     Ngo toju re titi.


5.  Ki tun s'edidi mo 

     Sugbon iranti ni! 

     Pe gbogbo igbese mi ni 

     Emmanuel san.  Amin

English »

Update Hymn