HYMN 496

C.M.S 584 t.H.C 318 C.M (FE 522)
"Eniti o si tan gbogbo re" - Ps.103:3



1.  ENIT‘O la ju afoju 

     Ti O mu ope gbon 

     At’enit'O da imole 

     Fun eni okunkun.


2.  Enit'O le fi agbara 

     F’awon olokunrun 

     Ti O si fi emi iye 

     Fun awon t'o ti ku.


3.  Eni fi ‘dasile f'okan 

     T'O gb’eni subu nde

     T’O si pa ibanuje da 

     S’orin pelu iyin.


4.  Wo Onisegun okan mi 

     Si O l’awa nkorin

     Titi aiye o fi d’opin 

     Tire l’ope o se.  Amin 

English »

Update Hymn