HYMN 490

C.M.S 429 t.H.C 428 C.M (FE 516)
"E ma ru eru omonikeji nyin" - Gal. 6



1.  WO orisun Ohun rere 

     Awa fe se ‘fe re;

    Ohun wo l‘a le fifun O 

    Oba gbogbo aiye?


2.  L'aiye yi, Wo ni otosi 

     T’o je enia Re

     Oruko won n’lwo njewo 

     Niwaju Baba Re.


3.  Gba nwon ba nke n’inira won 

     Ohun Re l’awa ngbo

     Gba ba si nse itoju won

     Awa nse 'toju Re.


4.  Jesu, masai gba ore wa

     Si f'ibukun Re si

     Ma f’ibukun Re s'ebun wa 

     Fun awon t‘a nfi fun.


5.  Fun baba, Omo at’Emi

     Olorun ti a nsin

     Ni ki a ma fi ogo fun

     Titi aiyeraiye.  Amin

English »

Update Hymn