HYMN 458

S.21 P.M (FE 483) 
“Awon omo kiniun a ma se alaini, 
ebi a si ma pa won.. awon ti nwa 
Oluwa ki yio se alaini” - PS.34:10




1.  LI onakona, “Oluwa y’o pese’

     O le s’ais’ona mi, o le s’aise tire 

     Sugbon lona ‘ra Re, li On o pese!


2.  Lakoko to ye, “Oluwa y’o pese’ 

     O Ie s’aise temi, o le s’ aise tire 

     Lakoko t’ara Re, li On o pese!


3.  Ma beru, ‘tori “Oluwa y’o pese", 

     Eyi n’ileri Re, ko s’oro ti O so, 

     Ti si yipada, ‘Oluwa o pese.


4.  Yan lo l'aibikita, okun y'o pinya

     O f‘orin isegun se ona re logo,

     A o jumo gberin, ‘Oluwa y’o pese.  Amin

English »

Update Hymn