HYMN 454

K. 117 .t.H.C. 320 C.M (FE 480) 
"O si pe oruko ibe na ni
Jehovah Jire" - Gen.22:14



1.  KO to k'awon mimo beru

     Ki nwon so ‘reti nu

     ‘Gba nwon ko reti ‘ranwo Re, 

     Olugbala y’o de.

Egbe:  Ka d'amure lati jagun

           Ka d'amure lati jagun

           Ka d'amure e

           Ka d'amure e

           Ka d'amure lati jagun.


2.  Nigbati Abraha mu obe 

     Olorun ni ‘Duro" 

     Agbo ti o wa lohun ni 

    Y'o dipo omo na.

Egbe:  Ka d'amure lati jagun...


3.  ‘Gba Jona ri sinu omi

     Ko ro lati yo mo 

     Sugbon Olorun ran eje 

     T'o gbe lo s’ebute.

Egbe:  Ka d'amure lati jagun...


4.  B'iru ipa at‘ife yi

     Ti pio l'oro Re to 

     Emi ba ma k‘aniyan mi 

     Le Oluwa lowo.

Egbe:  Ka d'amure lati jagun...


5.  E duro de iranwo Re 

     B'o tile pe, duro

     B'ileri na tile fa ‘le

     Sugbon ko le pe de.

Egbe:  Ka d'amure lati jagun

           Ka d'amure lati jagun

           Ka d'amure e

           Ka d'amure e

           Ka d'amure lati jagun.  Amin

English »

Update Hymn