HYMN 416

(FE 439) C.M.S 531 C.H. t.H.C 145 7s 
"‘Enyin o si saferi mi, e o si ri mi, 
ti e ba fi gbogbo okan nyin wa mi”
 - Jer. 29:13



1.  OLUWA, awa’do Re 

     L’ese Re l’a kunle si 

     A! ma kegan ebe wa

     Ao wa lasan bi!


2.  L’ ona to O yan fun wa 

     L’a nwa O lowolowo 

     Oluwa a ki o lo

     Titi ‘Wo o bukun wa.


3.  Ranse lat’oro Re wa 

     Ti O fi ayo‐fun wa 

     Je ki emi Re ko fun 

     Okan wa ni igbala.


4.  Jek’a wa, k’a si ri O

     Ni Olorun Olore

     W’alasian, da ‘gbekun si,

     Ki gbogbo wa yo si O.  Amin

English »

Update Hymn