HYMN 412

H.C. 273 D. 7s 6s (FE 434)
"E ma gbadura li aisimi" - 1 Tess. 5:17



1.  LO l’oro kutukutu 

     Lo, ni osangangan 

     Lo, ni igba asale 

     Lo ni oganjo oru, 

     Lo, t’iwo t’inu rere 

     Gbagbe ohun aiye 

     Si kunle n’iyewu re 

     Gbadura nikoko.


2.  Ranti awon t’o fe o 

     At' awon t'iwo fe 

     Awon t‘o korira re

     Si gbadura fun won 

     Lehin na, toro ‘bukun 

     Fun ‘wo tikalare 

     Ninu adura re, ma

     Pe oruko Jesu.


3.  B’aiye ati gbadura 

     Ni koko ko si si

     T'okan re fe gbadura 

     Gbat’ore yi o ka 

     Ghana, adura jeje 

     Lat’ inu okan re

     Y’o de odo Olorun 

     Olorun Alanu.


4.  Ko si ay, kan l’aiye 

     T’o si ju eyi lo

     Nit' agbara t'a fun wa 

     Lati ma gbadura

     ‘Gba t’inu re ko ba dun 

     Jek‘okan re wole

     Ninu ayo re gbogbo 

     Ranti or'ofe re.  Amin

English »

Update Hymn