HYMN 410

(FE432)
C.M.S 301, H.C 276. C.M
"Olorun aiyeraiye ki isare, ko si a 
awari oye Re" - Isa 40:28



1.  OJU kan mbe ti ki togbe

     Nigbat’ile ba su

     Eti kan mbe ti ki ise

     ‘Gbat orun ba wo.


2.  Apa kan mbe ti ko le re 

     Gba ‘pa enia pin

     Ife kan mbe ti ko le ku 

     Gba fe aiye ba ku.


3.  Oju na nwo awon Serafu 

     Apa na d’orun mu

     Eti na kun f’orin Angel

     lfe na ga loke.


4.  lpa kan l’enia le lo 

     Gbat ipa gbogbo pin 

     Lati ri oju at’apa

     Ati ife nla na.


5.  lpa na ni adura wa

     Ti nlo ‘waju ite

     To nmi owo t’o s’aiye ro 

     Lati mu ‘gbala wa.


6.  Iwo t’anu re ko lopin 

     T’ife Re ko le ku

     Je k’a n’igbagbo at’ife 

     K’a le ma gbadura.  Amin

English »

Update Hymn