HYMN 405

O.t.H. 229 C.M. (FE 428) 
"Mo ri oro Re mo si je won " -  Jer. 15:16



1.  BIBELI iwe aiyeraiye

     Tani le r’idi re? 

     Tani Ie so idide re? 

     Tani le m'opin re?


2.  Asiri Olodumare 

     Iko Oba orun 

     Ida t’o pa oro iku 

     Aworan Olorun.


3.  Okan ni O larin opo 

     Iwe aiye ‘gbani

     lwo l‘o s’ona igbala 

     Di mimo f’araiye.


4.  Isura ti Metalokan 

     Oba nla t’o gunwa

     Jo, tumo ara Re fun mi 

     Ki m'ye siyemeji.


5.  Ki m’si o p pelu adura

     Ki ‘m’k‘ eko ninu re 

     Iwo lwe Aiyeraiye, 

     F’ife Jesu han mi.  Amin

English »

Update Hymn